Isaiah 17:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìlú olódi kò ní sí mọ́ ní Efuraimu, kò sì ní sí ìjọba mọ́ ní Damasku, àwọn tí wọ́n bá ṣẹ́kù ní Siria yóo sì dàbí ògo àwọn ọmọ Israẹli, OLUWA àwọn ọmọ ogun ló sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Odi kì yio si si mọ ni Efraimu, ati ijọba ni Damasku, ati iyokù ti Siria: nwọn o dabi ogo awọn ọmọ Israeli, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìlú olódi ni yóò pòórá kúrò ní Éfáímù, àti agbára ọba kúrò ní Dámásíkù; àwọn àsẹ́ku Árámù yóò dá gẹ́gẹ́ bí ògo ti àwọn Ísírẹ́lì,” ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí.