Isaiah 17:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Tó bá di ìgbà náà, a óo rẹ ògo àwọn ọmọ Israẹli sílẹ̀, ọrọ̀ wọn yóo di àìní.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ na yio si ṣe, a o mu ogo Jakobu dinkù, ati sisanra ara rẹ̀ li a o sọ di rirù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ọjọ́ náà ni ògo Jákọ́bù yóò ṣá; ọ̀rá ara rẹ̀ yóò ṣòfò dànù.