Isaiah 17:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Yóo dàbí ìgbà tí eniyan kórè ọkà lóko, tí ó kó ṣiiri ọkà kún apá. Tí àwọn kan tún wá ṣa ọkà yòókù, tí àwọn tí wọn kọ́ kórè ọkà gbàgbé ní àfonífojì Refaimu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si dabi igbati olukorè nkó agbado jọ, ti o si nfi apá rẹ̀ rẹ́ ipẹ́-ọkà yio si dabi ẹniti nkó ipẹ́-ọkà jọ ni afonifoji Refaimu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yóò sì dàbí ìgbà tí olùkóórè kó àwọn irúgbìn tí ó dúró jọ tí ó sì ń kórè irúgbìn pẹ̀lú apá rẹ̀— àti gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí ènìyàn pa ọkà ní àfonífojì ti Réfémù.