Isaiah 19:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn eniyan pataki ilẹ̀ náà yóo di ẹni ilẹ̀, ìbànújẹ́ yóo sì bá àwọn alágbàṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A o si fọ́ wọn ni ipilẹ rẹ̀, gbogbo awọn alagbàṣe li a o bà ni inu jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ń ṣiṣẹ́ aṣọ yóò rẹ̀wẹ̀sì, gbogbo àwọn oníṣẹ́ oṣù ni àìṣàn ọkàn yóò ṣe.