Isaiah 19:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òmùgọ̀ ni àwọn olórí wọn ní Soani; ìmọ̀ràn wèrè sì ni àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ìgbìmọ̀ Farao ń fún eniyan. Báwo ni eniyan ṣe lè sọ fún Farao pé, “Ọmọ Ọlọ́gbọ́n eniyan ni mí, ọmọ àwọn ọba àtijọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ òpe ni awọn ọmọ-alade Soani, ìmọ awọn ìgbimọ ọlọgbọn Farao di wère: ẹ ha ti ṣe sọ fun Farao, pe, Emi li ọmọ ọlọgbọn, ọmọ awọn ọba igbãni?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn oníṣẹ́ Ṣóánì ti di aláìgbọ́n, àwọn ọlọgbọ́n olùdámọ̀ràn Fáráò ń mú ìmọ̀ràn àìgbọ́n wá. Báwo ló ṣe lè sọ fún Fáráò pé, “Mo jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyàn, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn àwọn ọba ijọ́un.”