Isaiah 19:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n rẹ dà? Níbo ni wọ́n wà kí wọ́n sọ fún ọ, kí wọ́n sì fi ohun tí OLUWA àwọn ọmọ ogun pinnu láti ṣe sí Ijipti hàn ọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn dà? awọn ọlọgbọn rẹ dà? si jẹ ki wọn sọ fun ọ nisisiyi, si jẹ ki wọn mọ̀ ete ti Oluwa awọn ọmọ-ogun ti pa le Egipti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbo ni àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyàn rẹ wà báyìí? Jẹ́ kí wọn fi hàn ọ́ kí wọn sì sọ ọ́ di mímọ̀ ohun tí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ti pinnu lórí Éjíbítì.