Isaiah 19:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn olórí wọn ní Soani ti di òmùgọ̀, àwọn olórí wọn ní Memfisi sì ti gba ẹ̀tàn; àwọn tí wọ́n jẹ́ òpómúléró ní ilẹ̀ Ijipti ti ṣi Ijipti lọ́nà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ-alade Soani di aṣiwère, a tàn awọn ọmọ-alade Nofi jẹ; ani awọn ti iṣe pataki ẹyà rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn oníṣẹ́ Ṣóárì ti di aláìgbọ́n, a ti tan àwọn adarí Méḿfísì jẹ; àwọn òkúta igunlé tí í ṣe ti ènìyàn rẹ ti ṣi Éjíbítì lọ́nà.