Isaiah 19:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn n óo fi Ijipti lé aláìláàánú akóniṣiṣẹ́ kan lọ́wọ́ ìkà kan ni yóo sì jọba lé wọn lórí, bẹ́ẹ̀ ni Oluwa, OLUWA àwọn ọmọ ogun wí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun wipe, Awọn ara Egipti li emi o fi le oluwa onrorò li ọwọ́; ọba ti o muna yio ṣe akoso wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò fi Éjíbítì lé agbára àwọn ìkà amúnisìn lọ́wọ́, ọba aláìláàánú ni yóò jọba lé wọn lórí,” ni OLÚWA, OLÚWA Alágbára wí.