Isaiah 19:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo odò wọn yóo máa rùn, gbogbo àwọn odò tí ó ṣàn wọ odò Naili ní Ijipti, ni yóo fà, tí yóo sì gbẹ: Gbogbo koríko odò yóo rà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Odò yio si di rirùn; odò ãbo li a o sọ di ofo, ti a o si gbọ́n gbẹ; oko-odò ati iyè yio rọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àyasí omi yóò máa rùn; àwọn odò ilẹ̀ Éjíbítì yóò máa dínkù wọn yóò sì gbẹ. Àwọn koríko odò àti ìrẹ̀tẹ̀ yóò gbẹ,