Isaiah 19:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Etí odò Naili yóo di aṣálẹ̀, gbogbo ohun tí wọ́n bá gbìn sibẹ yóo gbẹ, ẹ̀fúùfù óo sì gbá wọn dànù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oko-tutù ni ipadò, li ẹnu odò, ati ohun gbogbo ti a gbìn sipadò, ni yio rọ, yio funka, kì yio si si mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àwọn igi ìpadò Náì pẹ̀lú, tí ó wà ní oríṣun odò Náì. Gbogbo oko tí a dá sí ìpadò Náì yóò gbẹ dànù tí yóò sì fẹ́ dànù tí kò sì ní sí mọ́.