Isaiah 19:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn apẹja tí ń fi ìwọ̀ ninu odò Naili yóo ṣọ̀fọ̀, wọn óo sì sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn; àwọn tí ń fi àwọ̀n pẹja yóo kérora.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn apẹja yio gbàwẹ pẹlu, ati gbogbo awọn ti nfì ìwọ li odò yio pohùnrére-ẹkun; ati awọn ti nda àwọn li odò yio sorikọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn apẹja yóò ṣunkún kíkorò, gbogbo àwọn tí ó ń ju ìwọ̀ sínú Náí; yóò sì máa rùn.

Recommended Reading