Isaiah 2:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn óo wọ inú pàlàpálá àpáta, ati inú ihò àwọn òkè gíga; nígbà tí wọn bá ń sá fún ibinu OLUWA, ati ògo ọlá ńlá rẹ̀, nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati lọ sinu pàlapala apata, ati soke apata sisán, nitori ibẹru Oluwa, ati nitori ogo ọlanla rẹ̀; nigbati o ba dide lati mì ilẹ aiye kijikiji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò ṣálọ sínú ihò ìsàlẹ̀ àpáta àti sínú ihò pàlàpálá àpáta kúrò lọ́wọ́ ìpayà OLÚWA àti ògo ọlá ńlá rẹ̀, nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.