Isaiah 2:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ilẹ̀ wọn kún fún oriṣa, wọ́n ń bọ iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn, wọ́n ń wólẹ̀ fún ohun tí wọ́n fọwọ́ ara wọn ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ wọn kún fun oriṣa pẹlu; nwọn mbọ iṣẹ ọwọ́ ara wọn, eyiti ika awọn tikalawọn ti ṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ère, wọ́n sì ń foríbalẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn, èyí tí ìka ọwọ́ àwọn tikálára wọn ti ṣe.