Isaiah 2:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni eniyan ṣe tẹ ara rẹ̀ lórí ba tí ó sì rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀. Oluwa, máṣe dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Enia lasan si foribalẹ, ẹni-nla si rẹ̀ ara rẹ̀ silẹ; nitorina má ṣe darijì wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni a ó ṣe rẹ ènìyàn sílẹ̀ ìran ọmọ ènìyàn ni yóò sì di onírẹ̀lẹ̀, má ṣe dáríjìn wọ́n.