Isaiah 20:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìbẹ̀rù-bojo yóo dé ba yín, ojú yóo sì tì yín; nítorí Kuṣi ati Ijipti tí ẹ gbójú lé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ̀ru yio si bà wọn, oju o si tì wọn fun Etiopia ireti wọn, ati fun Egipti ogo wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Kúṣì tí wọ́n sì ń fi Éjíbítì yangàn ni ẹ̀rù yóò dé bá tí a ó sì dójútì wọ́n.