Isaiah 21:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Edomu nìyí: Ẹnìkan ń pè mí láti Seiri Ó ní: “Aṣọ́nà, Òru ti rí o? Aṣọ́nà, àní òru ti rí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọ̀rọ-ìmọ niti Duma. O ké si mi lati Seiri wá, Oluṣọ́, oru ti ri? Oluṣọ́ oru ti ri?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀rọ̀ ìmọ̀ tí ó kan Dúmáhì: Ẹnìkan ké sí mi láti Séírì wá “Alóre, kí ló kù nínú òru náà?”