Isaiah 21:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ń sá fún idà, wọ́n sá fún idà lójú ogun. Wọ́n ń sá fún àwọn tafàtafà, wọ́n sá fún líle ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori nwọn nsá fun idà, fun idà fifayọ, ati fun ọrun kikàn, ati fun ibinujẹ ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sá kúrò lọ́wọ́ idà, kúrò lọ́wọ́ idà tí a fàyọ, kúrò lọ́wọ́ ọrun tí ó lò àti kúrò nínú ìgbóná ogun.