Isaiah 21:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
díẹ̀ ni yóo sì kù ninu àwọn tafàtafà alágbára ọmọ Kedari; nítorí OLUWA Ọlọrun Israẹli ló sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iyokù ninu iye awọn tafàtafà, awọn alagbara ninu awọn ọmọ Kedari yio dinkù: nitori Oluwa Ọlọrun Israeli ti wi i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tafàtafà tí ó ṣálà, àwọn jagunjagun Kédárì kò ní tó nǹkan” OLÚWA, Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ó ti sọ̀rọ̀.