Isaiah 21:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹni tí ń ṣọ́nà kígbe pé: “OLUWA mi, lórí ilé-ìṣọ́ ni èmi í dúró sí lojoojumọ, níbi tí a fi mí ṣọ́, ni èmi í sì í wà ní òròòru.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si kigbe pe, kiniun kan: Oluwa mi, nigbagbogbo li emi nduro lori ile-iṣọ li ọsan, a si fi mi si iṣọ mi ni gbogbo oru:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni alóre náà kígbe, “Láti ọjọ́ dé ọjọ́, OLÚWA mi, mo dúró ní ilé ìṣọ́, alaalẹ́ ni mo fi ń wà nípò mi.