Isaiah 22:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ní, “Lọ bá Ṣebina, iranṣẹ ọba, tí ó jẹ́ olórí ní ààfin ọba, Kí o bi í pé:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, pe, Lọ, tọ olutọju yi lọ, ani tọ Ṣebna lọ, ti iṣe olori ile,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni ohun tí OLÚWA, àní OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí: Lọ, sọ fún ìríjú yìí pé, fún Ṣébínà, ẹni tí ààfin wà ní ìkáwọ́ọ rẹ̀: