Isaiah 22:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ẹ̀yin tí ìlú yín kún fún ariwo, tí ẹ jẹ́ kìkì ìrúkèrúdò ati àríyá? Gbogbo àwọn tí ó kú ninu yín kò kú ikú idà, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò kú lójú ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti o kún fun ìrukerudo, ilu aitòro, ilu ayọ̀: a kò fi idà pa awọn okú rẹ, bẹ̃ni nwọn kò kú li ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ìlú tí ó kún fún dàrúdàpọ̀, Ìwọ ìlú rúkèrúdò òun rògbòdìyàn Àwọn tó ṣubú nínú un yín ni a kò fi idà pa, tàbí ojú ogun ni wọ́n kú sí.