Isaiah 22:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ìjòyè ìlú yín parapọ̀ wọ́n sálọ, láì ta ọfà ni ọ̀tá mú wọn. Gbogbo àwọn tí wọn rí ni wọ́n mú, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti sá jìnnà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn alakoso rẹ ti jumọ sa lọ, awọn tafàtafà ti dì wọn ni igbekun: gbogbo awọn ti a ri ninu rẹ li a dì jọ, ti o ti sa lati okere wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn olóríi yín ti jùmọ̀ sálọ; a ti kó wọn nígbékùn láì lo ọrun ọfà. Ẹ̀yin tí a mú ni a ti kó lẹ́rú papọ̀, lẹ́yìn tí ẹ ti sá nígbà tí ọ̀ta sì wà lọ́nà jínjìnréré.