Isaiah 22:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, ni mo ṣe sọ pé, “Ẹ ṣíjú kúrò lára mi ẹ jẹ́ kí n sọkún, kí n dami lójú pòròpòrò, ẹ má ṣòpò pé ẹ óo rẹ̀ mí lẹ́kún, nítorí ìparun àwọn ará Jerusalẹmu, àwọn eniyan mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li emi ṣe wipe, Mu oju kuro lara mi; emi o sọkun kikoro, má ṣe ãpọn lati tù mi ni inu, nitori iparun ti o ba ọmọbinrin enia mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni mo wí pé, “Yípadà kúrò lọ́dọ̀ mi: jẹ́ kí n ṣunkún kíkorò. Má ṣe gbìyànjú àti tùmí nínú nítorí ìparun àwọn ènìyàn mi.”

Recommended Reading