Isaiah 22:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ti ya ọjọ́ kan sọ́tọ̀, ọjọ́ ìrúkèrúdò ati ìdágìrì ati ìdàrúdàpọ̀, ní àfonífojì ìran. Ọjọ́ wíwó odi ìlú palẹ̀ ati igbe kíké láàrin àwọn òkè ńlá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ọjọ wahála ni, ati itẹmọlẹ, ati idãmu, nipa Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun ni afonifoji ojuran, o nwó odi palẹ, o si nkigbe si oke-nla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan tí rúkèrúdò, rògbòdìyàn àti ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ ní àfonífojì ìmọ̀, ọjọ́ tí a ń wó ògiri lulẹ̀ àti síṣun ẹkún lọ sí àwọn orí òkè.