Isaiah 22:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó ti tú aṣọ lára Juda. Ní ọjọ́ náà, ẹ gbẹ́kẹ̀lé àwọn ohun ìjà tí ó wà ninu Ilé-Igbó,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si ri iboju Juda, iwọ si wò li ọjọ na ihamọra ile igbó.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
gbogbo ààbò Júdà ni a ti ká kúrò. Ìwọ sì gbójú sókè ní ọjọ́ náà sí àwọn ohun ìjà ní ààfin ti inú ihà,