Isaiah 23:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ti na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun Ó ti mi àwọn orílẹ̀-èdè jìgìjìgì. Ó ti pàṣẹ nípa ilẹ̀ Kenaani pé kí wọ́n pa gbogbo ibi ààbò rẹ̀ run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O nà ọwọ́ rẹ̀ jade si oju okun, o mì awọn ijọba: Oluwa ti pa aṣẹ niti Kenaani, lati run agbàra inu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA ti na ọwọ́ọ rẹ̀ jáde sí orí òkun ó sì mú kí àwọn ilẹ̀ ọba wárìrì. Ó ti pa àṣẹ kan tí ó kan Fonísíà pé kí a pa ilé ààbò rẹ̀ run.