Isaiah 23:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
wọ́n gba orí alagbalúgbú omi kọjá lọ. Èrè yín ni ọkà ìlú Sihori, ìkórè etí odò Naili. Ẹ̀yin ni ẹ̀ ń ṣòwò káàkiri àgbáyé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati nipa omi nla iru Sihori, ikorè odò, ni owo ọdun rẹ̀; on ni ọjà awọn orilẹ-ède.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti orí àwọn omi ńlá ni irúgbìn oníhóró ti ilẹ̀ Ṣíhórì ti wá ìkóórè ti Náì ni owóòná Tírè, òun sì ti di ibùjókòó ọjà fún àwọn orílẹ̀ èdè.