Isaiah 24:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ariwo ta lóde nítorí kò sí ọtí waini, oòrùn ayọ̀ ti wọ̀; ayọ̀ di àwátì ní ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Igbe fun ọti-waini mbẹ ni igboro; gbogbo ayọ̀ ṣú òkunkun, aríya ilẹ na lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní òpópónà ni wọ́n ti ń kígbe fún wáìnì gbogbo ayọ̀ọ wọn ti di ìbànújẹ́, gbogbo àríyá ni a lé kúrò lórí ilẹ̀ ayé.