Isaiah 24:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ní yóo rí ní ilẹ̀ ayé, láàrin àwọn orílẹ̀-èdè bí igi olifi tí a ti gbọn gbogbo èso rẹ̀ sílẹ̀, lẹ́yìn tí a ti kórè tán ninu ọgbà àjàrà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati yio ri bayi li ãrin ilẹ lãrin enia na, bi mimì igi olifi, ati bi pipẽṣẹ eso-àjara nigbati ikorè àjara tán.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni yóò sì rí ní orí ilẹ̀ ayé àti láàrin àwọn orílẹ̀ èdè pẹ̀lú, gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí a lu igi ólífì, tàbí gẹ́gẹ́ bí i pàǹtí tí ó ṣẹ́kù lẹ́yìn tí a kórè èso tán.