Isaiah 24:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n ń kọrin ayọ̀, wọ́n ń yin OLUWA lógo láti ìhà ìwọ̀-oòrùn wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o gbe ohùn wọn soke, nwọn o kọrin nitori ọla-nla Oluwa, nwọn o kigbe kikan lati okun wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gbé ohùn wọn ṣókè, wọ́n sì hó fún ayọ̀; láti ìwọ̀ oòrùn ni wọn yóò ti polongo ọlá-ńlá OLÚWA.