Isaiah 24:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní àkókò náà, OLUWA yóo fìyà jẹ àwọn ogun ọ̀run, lọ́run; ati àwọn ọba ayé, lórí ilẹ̀ ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe li ọjọ na, Oluwa yio bẹ̀ ogun awọn ẹni-giga ni ibi-giga wò, ati awọn ọba aiye li aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ náà ni OLÚWA yóò jẹ ẹ́ níyà gbogbo agbára tí ó wà lókè lọ́run àti àwọn ọba tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé.