Isaiah 24:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A óo gbá gbogbo wọn jọ pọ̀ sinu kòtò bí ẹlẹ́wọ̀n, wọn óo wà ní àtìmọ́lé ninu ẹ̀wọ̀n. Lẹ́yìn ọpọlọpọ ọjọ́, a óo fìyà jẹ wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A o si ko wọn jọ pọ̀, bi a iti kó ara tubu jọ sinu ihò, a o tì wọn sinu tubu, lẹhin ọjọ pupọ̀ li a o si bẹ̀ wọn wò.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó dà wọ́n papọ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́wọ̀n tí a dè nínú un túbú, a ó tì wọ́n mọ́ inú ẹ̀wọ̀n a ó sì jẹ wọ́n ní ìyà lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́.