Isaiah 24:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ogun yóo kó ilé ayé, yóo di òfo patapata. Nítorí OLUWA ni ó sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ yio di ofo patapata, yio si bajẹ patapata: nitori Oluwa ti sọ ọ̀rọ yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilé ayé ni a ó sọ di ahoro pátapáta a ó sì jẹ gbogbo rẹ̀ run. OLÚWA ni ó ti sọ ọ̀rọ̀ yìí.