Isaiah 24:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ ń ṣọ̀fọ̀, gbogbo nǹkan ń rọ. Ayé ń joró, ó sì ń ṣá àwọn ọ̀run ń joró pẹlu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ̀ nṣọ̀fọ o si nṣá, aiye nrù o si nṣá, awọn ẹni giga ilẹ njoro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ ayé ti gbẹ ó sì ṣá, ayé ń ṣòjòjò, àárẹ̀ mú un, àwọn ẹni gíga ilẹ̀ ayé wà nínú ìpọ́njú