Isaiah 24:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn kò mu ọtí níbi tí wọ́n ti ń kọrin mọ́ ọtí líle sì korò lẹ́nu àwọn tí ń mu ún.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kì yio fi orin mu ọti-waini mọ́; ọti-lile yio koro fun awọn ti nmu u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò ṣeéṣe fún wọn láti máa mu wáìnì pẹ̀lú orin kíkọ mọ́ ọtí líle ti di ìkorò fún àwọn ọ̀mu.