Isaiah 25:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà àwọn alágbára yóo máa yìn ọ́ ìlú àwọn orílẹ̀-èdè aláìláàánú yóo bẹ̀rù rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni awọn alagbara enia yio yìn ọ li ogo, ilu orilẹ-ède ti o ni ibẹ̀ru yio bẹ̀ru rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà àwọn ènìyàn alágbára yóò bọ̀wọ̀ fún ọ; àwọn ìlú orílẹ̀ èdè aláìláàánú yóò bọlá fún ọ.