Isaiah 25:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó dàbí ooru ninu aṣálẹ̀. O pa àwọn àjèjì lẹ́nu mọ́; bí òjìji ìkùukùu tií sé ooru mọ́, bẹ́ẹ̀ ni o ṣe dá orin mọ́ àwọn oníjàgídíjàgan lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o mu ariwo awọn alejo rọlẹ, gẹgẹ bi oru nibi gbigbẹ; ani oru pẹlu ojiji awọsanma: a o si rẹ̀ orin-ayọ̀ awọn ti o ni ibẹ̀ru silẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àti gẹ́gẹ́ bí ooru ní ihà. O mú ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ bá rògbòdìyàn àwọn àjèjì, gẹ́gẹ́ bí òjìji kùrukùru ṣe ń dín ooru kù, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni orin àwọn ìkà yóò dákẹ́.