Isaiah 26:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ìwọ OLUWA ti mú kí orílẹ̀-èdè náà pọ̀ sí i, OLUWA, o ti bukun orílẹ̀-èdè náà, gbogbo ààlà ilẹ̀ náà ni o ti bì sẹ́yìn, o sì ti buyì kún ara rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti mu orilẹ-ède bi si i, Oluwa, iwọ ti mu orilẹ-ède bi si i; iwọ ti di ẹni-ãyin li ogo: iwọ ti sún gbogbo ãlà siwaju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ti mú orílẹ̀ èdè gbòòrò, OLÚWA; ìwọ ti mú orílẹ̀ èdè bí sí i. Ìwọ ti gba ògo fún araàrẹ; ìwọ ti sún gbogbo àwọn ààlà ilẹ̀ ṣẹ́yìn.