Isaiah 28:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo ìgbà tí ó bá ti ń ṣẹlẹ̀ ni yóo máa ba yín tí yóo máa gba yín lọ. Yóo máa ṣẹlẹ̀ láàárọ̀, yóo sì máa ṣẹlẹ̀ tọ̀sán-tòru. Ẹ̀rù yóo ba eniyan, tí eniyan bá mọ ìtumọ̀ ìkìlọ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Niwọn igbati o ba jade lọ ni yio mu nyin: nitori ni gbogbo owurọ ni yio rekọja, li ọsan ati li oru: kiki igburo rẹ̀ yio si di ijaiyà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbàkúùgbà tí ó bá ti wá ni yóò máa gbé ọ lọ, ni àràárọ̀, ní ọ̀sán àti ní òru, ni yóò máa fẹ́ kọjá lọ.” Ìmòye ọ̀rọ̀ ìmọ̀ yìí yóò máa mú ìpayà ńlá wá.