Isaiah 28:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọ̀dọ̀ OLUWA àwọn ọmọ ogun ni ìmọ̀ yìí ti ń wá pẹlu, ìmọ̀ràn rẹ̀ yani lẹ́nu; ọgbọ́n rẹ̀ ni ó sì ga jùlọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi pẹlu ti ọdọ Oluwa awọn ọmọ-ogun wá, ẹniti o kún fun iyanu ni ìmọ, ti o tayọ ni iṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo èyí pẹ̀lú ti ọ̀dọ̀ OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wá, oníyanu ní ìmọ̀ràn àti ológo ní ọgbọ́n.