Isaiah 28:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ọjọ́ náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun yóo jẹ́ adé ògo ati adé ẹwà, fún àwọn tí ó kù ninu àwọn eniyan rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ na li Oluwa awọn ọmọ-ogun yio jẹ ade ogo, ati ade ẹwà fun iyokù awọn enia rẹ̀,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ náà OLÚWA àwọn ọmọ-ogun yóò jẹ́ adé tí ó lógo, Òdòdó tí ó lẹ́wà fún àwọn ènìyàn an rẹ̀ tí ó ṣẹ́kù.