Isaiah 29:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí pé àwọn aláìláàánú yóo di asán, àwọn apẹ̀gàn yóo di òfo; àwọn tí ń wá ọ̀nà láti ṣe ibi yóo parun;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori a sọ aninilara na di asan, a si pa ẹlẹgàn run, a si ké gbogbo awọn ti nṣọ́ aiṣedede kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Aláìláàánú yóò pòórá, àwọn tí ń ṣẹlẹ́yà yóò dàwátì, gbogbo àwọn tí ó ní ojú ibi ni a ó ké lulẹ̀—