Isaiah 29:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn tí ń fi ọ̀rọ̀ ẹnu sọ eniyan di ẹlẹ́ṣẹ̀, tí ń dẹ tàkúté sílẹ̀ fún ẹni tí ń tọ́ni sọ́nà, tí wọ́n sì ń fi àbòsí tí kò nídìí ti olódodo sí apá kan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o dá enia li ẹbi nitori ọ̀rọ kan, ti nwọn dẹkùn silẹ fun ẹniti o baniwi ni ẹnubodè, ti nwọn si tì olododo si apakan, si ibi ofo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àwọn tí wọ́n fi ọ̀rọ̀ kan mú ẹnìkan di ẹlẹ́bi, ẹni tí ń dẹkùn mú olùgbèjà ní kóòtù tí ẹ fi ẹ̀rí èkè dun aláìṣẹ̀ ní ìdájọ́.