Isaiah 29:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, OLUWA tí ó ra Abrahamu pada sọ nípa ilé Jakọbu pé, “Ojú kò ní ti Jakọbu mọ́ bẹ́ẹ̀ ni ojú rẹ̀ kò ní rẹ̀wẹ̀sì mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina bayi li Oluwa, ẹniti o rà Abrahamu padà wi, pe, niti ile Jakobu, oju kì yio tì Jakobu mọ bẹ̃ni oju rẹ̀ kì yio yipada mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, èyí ni ohun tí OLÚWA, ẹni tí ó ra Ábúráhámù padà sọ sí ilé Jákọ́bù: “Ojú kì yóò ti Jákọ́bù mọ́; ojúu wọn kì yóò sì rẹ̀wẹ̀sì mọ́.