Isaiah 29:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí ó ti ṣìnà ninu ẹ̀mí yóo ní òye; àwọn tí ń kùn yóo sì gba ẹ̀kọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn pẹlu ti o ṣinà nipa ẹmi, oye yio wá yé wọn, ati awọn ti nsọ bótibòti yio kọ́ ẹkọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn tí ń rìn ṣégeṣège ní ẹ̀mí yóò jèrè ìmọ̀; gbogbo àwọn tí ń ṣe àròyé yóò gba ìtọ́sọ́nà.”