Isaiah 29:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lójijì, kíá, OLUWA àwọn ọmọ ogun yóo dé ba yín, pẹlu ààrá, ati ìdágìrì, ati ariwo ńlá; ati ààjà, ati ìjì líle, ati ahọ́n iná ajónirun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ãrá, ìṣẹlẹ, ati iró nla, pẹlu ìji on ẹfúfu, ati ọwọ́ ajonirun iná ni a o fi bẹ̀ ọ wò lati ọdọ Oluwa awọn ọmọ-ogun wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA àwọn ọmọ-ogun yóò wá pẹ̀lú àrá, ilẹ̀ ríri àti ariwo ńlá àti ẹ̀fúúfù líle àti iná ajónirun orílẹ̀ èdè tí ó bá Áríẹ́lì jà, tí ó dojú ìjà kọ òun àti ilé olódì rẹ̀ tí ó sì dó tì í, yóò dàbí ẹni pé nínú àlá, bí ìran ní òru