Isaiah 3:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ègbé ni fún àwọn eniyan burúkú, kò ní dára fún wọn. Nítorí wọn óo jèrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun enia buburu! yio buru fun u: nitori ere ọwọ́ rẹ̀ li a o fi fun u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀gbé ni fún aṣebi! Ìparun wà lóríi wọn A ó sì san èrè iṣẹ́ tí ọwọ́ wọn ti ṣe fún wọn.