Isaiah 3:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA yóo mú kí orí àwọn obinrin Jerusalẹmu pá; yóo ṣí aṣọ lórí wọn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina Oluwa yio fi ẽpá lu atàri awọn ọmọbinrin Sioni, Oluwa yio si fi ihoho wọn hàn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà OLÚWA yóò mú egbò wá sórí àwọn obìnrin Ṣíónì, OLÚWA yóò sì pá wọn ní agbárí.”