Isaiah 3:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yóo mú àwọn alágbára ati àwọn ọmọ ogun kúrò, pẹlu àwọn onídàájọ́ ati àwọn wolii, àwọn aláfọ̀ṣẹ ati àwọn àgbààgbà;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alagbara ọkunrin, ati jagunjagun, onidajọ, ati wolĩ, ati amoye, ati agbà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àwọn akíkanjú àti jagunjagun, adájọ́ àti wòlíì, aláfọ̀sẹ àti alàgbà,