Isaiah 3:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọ̀fọ̀ ati ẹkún yóo pọ̀ ní ẹnu ibodè Jerusalẹmu. Yóo dàbí obinrin tí wọ́n tú sí ìhòòhò, tí ó jókòó ní ilẹ̀ẹ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn bodè rẹ̀ yio pohùnrere ẹkun, nwọn o si ṣọ̀fọ; ati on, nitori o di ahoro, yio joko ni ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn bodè Síònì yóò sunkún kíkorò, wọn ó ṣọ̀fọ̀, nítorí ó dahoro, yóò jókòó ní orí ilẹ̀.